• Skip to main content
  • Skip to primary sidebar
  • Privacy Policy

GMLyrics

Gospel and Christian Music Lyrics. Submit, Print and Download Christian and Gospel Music Lyrics By Artiste

You are here: Home / Yoruba Hymns / Ojo Nla L’ojo Ti Mo Yan (Yoruba Hymns)

Ojo Nla L’ojo Ti Mo Yan (Yoruba Hymns)

Ojo Nla L’ojo Ti Mo Yan

1. Ojo nla l’ ojo ti mo yan
Olugbala l’ Olorun mi;
Oye ki okan mi ma yo,
K’o si ro ihin na ka ‘le.

Ojo nla l’ ojo na!
Ti Jesu we ese mi nu
O ko mi ki nma gbadura
Ki nma sora ki nsi ma yo
Ojo nla l’ ojo na!
Ti Jesu we ese mi nu.

2. Ide mimo t’o s’ edidi
Eje mi f’ Eni ye ki nfe?
Jek’ orin didun kun ‘le Re
Nigba mo ban lo sin nibe.

3.Mo ti b’ Oluwa sadehun!
Mo di Tire, On di temi,
On l’o pe mi, ti mo si je,
Mo f’ ayo jipe mimo na.

4. Simi, okan aiduro mi,
Simi le Jesu Oluwa;
Ma f’ Oluwa re sile lai,
Lodo Re n’ ire re gbe wa.

5.‘Wo orun t’o gbo eje mi
Y’o ma tun gbo lojojumo,
Tit’ ojo t’ emi mi y’o pin,
Ti ngo mu majemu na se.

Other Yoruba Hymns Lyrics
[display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]

Check Out

  • Igbala! Iro ayo nla (Yoruba Hymns)
  • E sin Oluwa ninu ewa iwa mimo (Yoruba Hymns)
  • Jek’a jumo korin iyin (Yoruba Hymns)
  • Tayotayo l’awa (Yoruba Hymns)
  • Ijinle ni ife Jesu (Yoruba Hymns)
  • Iwo Olurapada wa (Yoruba Hymns)
  • Olorun Awamaridi (Yoruba Hymns)
  • Yin Oluwa, o to, o ye (Yoruba Hymns)
  • Gbo orin idasile (Yoruba Hymns)
  • Ngo f’okan ope korin ‘yin (Yoruba Hymns)

Search For Lyrics

Reader Interactions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Primary Sidebar

SEARCH FOR OTHER LYRICS

Recent Posts

  • Rawlins – Chukwu Buike Lyrics
  • Diya – Can’t Have Enough Ft. G-Wills Lyrics
  • Tochukwu Ibekwe (Mr Tunez) – NSO (Holy) Lyrics
  • Darasimi & Lawrence Oyor – 911 Lyrics
  • Sunnypraise Adoga – I Trust in You Lyrics

Copyright © 2023 GMLyrics