Home >> Yoruba Hymns

Jek’a jumo korin iyin (Yoruba Hymns)

1. Jek’a jumo korin iyin
Pel’awon Angeli
Egbegberun t’o yi ‘te ka
Okan ni ayo won

2. Odo-agutan ti a pa
Lo ye lati gbe ga
Nwon nkorin kikankikan pe
On lo ye lati yin

3. Tire l’ogo at’agbara
Iwo l’ola ye fun
Ope t’enu wa ko le so
Tire ni Oluwa

4. Gbogbo eda t’ile t’oke
Ati l’ofurufu
Ninu okun, labe ile
Nwon ngbe Oluwa ga

5. Ijo Akobi ti oke
Ijo ti nja l’aiye
Nwon nkorin iyin si Oba
T’o gunwa lori ‘te

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *