Skip to content
Home » Igbala! Iro ayo nla (Yoruba Hymns)

Igbala! Iro ayo nla (Yoruba Hymns)

  1. Igbala! Iro ayo nla
  Adun ni l’eti wa
  Itura f’okan t’o gbogbe
  T’o le eru wa lo

  Egbe
  Ogo, iyin, ope, ola
  Ni f’Od’agutan tit lai
  Jesu Kristi’ l’Olugbala wa
  Halleluyah! Halleluyah! Halleluyah!
  Yin Oluwa

  2. Igbala! Iwo l’ope ye
  Od’agutan t’a pa
  Igbala y’o m’okan way o
  Y’o si ma j’orin wa

  Egbe

  3. Igbala! Kede re kiri
  Jakejado aiye
  Awon ogun orun y’o ho
  Nwon o ba wa gberin

  Egbe

  Other Yoruba Hymns Lyrics
  [display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *