Mo Fi Gbogbo Re Fun Jesu (Yoruba Hymns)

Mo Fi Gbogbo Re Fun Jesu

1. Mo fi gbogbo re fun Jesu,
Patapata l’aiku kan,
Ngó ma fe, ngó si gbekele,
Ngó wa lodo re titi.

Egbe
Mo fi gbogbo re (2ce)
Fun o, Olugbala mi, ni
Mo fi won sile.

2. Mo fi gbogbo re fun Jesu,
Mo fi rele wole fun;
Mo fi gbadun ayé sile;
Gbami Jesu si gba mi

3. Mo fi gbogbo re fun Jesu,
se mi  ni Tire nikan
Jeki kun fun
Ki nmo pe ‘wo je temi’

4. Mo fi gbogbo  re fun Jesu
Mo fi ara mi fun o
F’ife at’agbara kun mi,
Ki ibukun re ba le mi.

5. Mo fi gbogbo re fun Jesu,
Mo mo p’emi ba le mi
A! ayo igbala kikun!
Ogo, ogo, f’ogo re.

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *