• Skip to main content
  • Skip to primary sidebar
  • Privacy Policy
GMLyrics Logo

GMLyrics

Gospel and Christian Music Lyrics. Submit, Print and Download Christian and Gospel Music Lyrics By Artiste

You are here: Home / Yoruba Hymns / Gbata B’Oluwa Rin (Yoruba Hymns)

Gbata B’Oluwa Rin (Yoruba Hymns)

Gbata B’Oluwa Rin

1. ‘Gbat a b’Oluwa rin
N’nu mole oro re
Ona wa yio to mole to
‘Gbata a ba nse ‘fe Re
On yio ma ba wa gbe
Ati awon t’o gbeke won le

Egbe
Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l’ayo n’nu Jesu
Ju pe k’a gbekele

2. Ko s’ohun t’o le de
L’oke tabi ni’le
T’o le ko agbara Re l’oju
Iyemeji, eru, ibanuje, ekun
Ko le duro bi a gbekele

3. Ko si wahala mo
Tabi ibanuje
O ti san gbogbo gbese’ wonyi
Ko si arokan mo, Tabi ifa juro
Sugbon bukun, b’a ba gbeke le

4. Ako le f’enu so
Bi ‘fe Re ti po to
Titi ao fi f’ara wa rubo
Anu ti o nfihan
At’ayo t’o nfun ni
Je ti awon ti o gbeke le

5. Ni ‘dapo pelu Re
Ao joko lese Re
Tabi ki a ma rin pelu Re
Awa yo gbo ti Re
A o jise  to ran wa
Ma beru sa gbekele nikan

Other Yoruba Hymns Lyrics
[display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]

Search For Lyrics

Reader Interactions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Primary Sidebar

Recent Posts

  • Eben – So Into You Lyrics
  • Moses Bliss – Glory Lyrics
  • Ku Yi Ta Wa’azi Wurin Mutane Duk
  • Da Duniyan Nan da Girmanta da Yawan Daɗin Rai
  • Charity Isi – Taking Back Lyrics
  • Patrick Elijah – Call it Forth Lyrics
  • Tim Godfrey – Follow Follow Ft. Greatman Takit Lyrics
  • Purist Ogboi – Yeshua Lyrics
  • GUC – My Flag Lyrics
  • Greatman Takit – Bulie Ft. Limoblaze Lyrics
  • Greatman Takit – Look What You’ve Done Lyrics
  • Ko’rale & GreatMan Takit – Commando Lyrics
  • Ebuka Songs – I Will Pray Lyrics
  • Dunsin Oyekan – Who is on The Lord’s Side Ft. Mercy Chinwo Lyrics
  • Dunsin Oyekan – Maranatha Lyrics
  • Dunsin Oyekan – Finger Of God Lyrics
  • Dunsin Oyekan – Stand In The Gap Lyrics
  • Dunsin Oyekan – Because He Is, I Am Lyrics
  • Dunsin Oyekan – When I See You Lyrics
  • Dunsin Oyekan – The Great Revivalist Lyrics

Copyright © 2023 GMLyrics