Gba Aye Mi, Oluwa (Yoruba Hymns)

Gba Aye Mi, Oluwa

1. Gba aye mi, Oluwa
Mo ya si mimo fun O
Gba gbogbo akoko mi
Ki won kun fun iyin re

2. Gba owo mi ko si je
Ki n ma lo fun ife Re
Gba ese mi ko si je
Ki won ma sare fun O

3. Gba ohun mi je ki n ma
Korin f’Oba mi titi
Gba ete mi, je ki won
Ma jise fun O titi

4. Gba wura, fadaka mi
Okan nki o da duro
Gba ogbon mi, ko si lo
Gege bi o ba ti fe

5. Gba ‘fe mi fi se Tire
Ki yo tun je temi mo
Gbokan mi, Tire ni se
Ma gunwa nibe titi

6. Gba feran mi, Oluwa
Mo fi gbogbo re fun O
Gbemi paapa latoni
Ki n je Tire titi lai.

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *