Skip to content
Home » Ewaoluwa – Mimo Ft. BBO Lyrics

Ewaoluwa – Mimo Ft. BBO Lyrics

  Lyrics for Mimo By Ewaoluwa Ft. BBO

  Awon ti won yin Olorin nigbgbo igba won joko won duro niwaju ite re  ko sohun ti won se
  won yin won ke mimo si atobiju si atofarati bi oke
  moni mo nso ti awon ti o wo aso funfun ti ogun ti olopin
  won ki Oba ti olafiwe
  won ki eniwaju ti nsiwaju ogun
  won ki eni eyin ti nkeyin ogun
  won ki eni nla ti n komo ye loju ogun

  awon ti o jade ninu iponju ti wonsi so won di funfun ninu eje odo agatuan
  won nbe niwaju ite olorun won si eniti ojoko lori ite ton siji bowon ebi ole pawon beni oungbe ole gbe won
  won korin titun ka niwaju ite na ati niwaju awon eda alaye merin ati awon agbagba merinlelogun o
  kosi eni ti ole mo orin na afi awon oke meje ole egbaaji eniyan eniyan  ti ati rapada ninu aye
  motun so ti angeli to fo lagbedemeji orun
  mojuba eniti o da orun ataye okun ati gbogbo orisun omi
  mo nko mimo si eni ti ote iyn isreali do
  Olorun to gun kuku leshin
  Olorun o ega fio fio eo lafiwe  be leo  lakawe
  ina ti njo ni papa ti igbe  orun oke to ga ju oke lo o
  modarapo mo awon ti orun
  awon ti won ko mimo o won se mimo
  mimo lawon torun ke o awon to woso fun fun togun tion lopin
  wonke mimi wonko mimi
  mimo mimo lawon torun ke

  awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
  awon ogun orun mmimo won ke mimo si onite ogo
  awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
  mo bawon ko mimo mimo si Oba ogo

  BBO
  Si eni mimo to nse mimo to wu iwa mimo o
  tawon agbagba merinlelogun nko mimo mimo si lojojumo eru re nba mi o
  emi tokoja imisi omo eniyan ipa tobori gbogbo
  ipa eda patapata bi ose wa ni gbara to
  ofi agbara re ni aye lara o eru re mba mi o e
  eyin lalasepe ayin lalasegbe eyin ni olorun to nse to muje oo
  gbogbo agbara laye ati orun inu ikawo re lowa o
  olorun odanikan sejoba bose wa je  eni mimo to otun fi aye sile o fun oni doti to fe sunmo o felese to fe mo e
  se kin maparo olori aye olgun ajoobo o eru re nba mi ooo ee
  awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
  awon ogun orun mmimo won ke mimo si onite ogo
  awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
  mo bawon ko mimo mimo si Oba ogo
  mimo re oba ogo mimo re oba eda mimo re oba ogo
  ogo oo mimo re oba ogo  (2ce)

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *