Ewaoluwa Ayoola – Imole Mi (My Light) Lyrics

Lyrics for Imole Mi (My Light) By Ewaoluwa Ayoola

You are the reason why I am here today
You never let me down
Your grace makes a difference in my life
You are my light ( 2 ce)

Ni igbakan ri ninu aye mi ti emi ko mo oruko olorun ko si ifokanbale kosi ayo oo oo o

Sugbon logan ti Jesu de laye mi gba atunse awa somi domo awemimo oo (2 x)

[Chorus]
Imole mi alakoso alaanu mi ese gan (4x)

CHANTS:
Oba to laye atorun
Oba to daohun gbogbo
sebi iwo lakode ile aye ba

Sebi iwo ladeyeba
Iwo lakoji kio

Tio oba ayebama kiyin agbe opa ase sile abo agbada kuro lorun afi idobale si aki oba to joba lo esu ri yin osa oo o lagbara yin po oni oba to po nipa ati agbara ni

Olohun wo olohun o le wotan

olorun ta wo tale wotan oba ta so tale so tan oruko tape tale pe tan

Jagunlabi nla onile ola oo

Oba to laye atorun omo onile nkiyin

Olumotimolehin olu gbe omo de ibi ogo

Oba toni kokoro ile ola lowo oo moteduru emi mogbe oruko yin ga oo jagunlabi nla

[Chorus]
Imole mi alakoso alaanu mi ese gan

Other Ewaoluwa Ayoola Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *