Lyrics for Imole Mi (My Light) By Ewaoluwa Ayoola Ft. David Oke
You are the reason why I am here today You never let me down Your grace makes a difference in my life You are my light ( 2 ce)
Ni igbakan ri ninu aye mi ti emi ko mo oruko olorun ko si ifokanbale kosi ayo oo oo o
sugbon logan ti Jesu de laye mi gba atunse awa somi domo awemimo oo (2 x)
CHORUS: Imole mi alakoso alaanu mi ese gan (4x)
CHANTS:
Oba to laye atorun
oba to daohun gbogbo
sebi iwo lakode ile aye ba
sebi iwo ladeyeba
iwo lakoji kio
tio oba ayebama kiyin agbe opa ase sile abo agbada kuro lorun afi idobale si aki oba to joba lo esu ri yin osa oo o lagbara yin po oni oba to po nipa ati agbara ni
olohun wo olohun o le wotan
olorun ta wo tale wotan oba ta so tale so tan oruko tape tale pe tan
jagunlabi nla onile ola oo
oba to laye atorun omo onile nkiyin
olumotimolehin olu gbe omo de ibi ogo
oba toni kokoro ile ola lowo oo moteduru emi mogbe oruko yin ga oo jagunlabi nla
CHORUS: Imole mi alakoso alaanu mi ese gan
Other Ewaoluwa Ayoola Lyrics [display-posts category=”Ewaoluwa Ayoola” exclude_current=”true”]
Leave a Reply