Elubaji Daniel – Ona Iyanu Lyrics

Lyrics for Ona Iyanu By Daniel Elubaji  Ft. Moses Olaboye & Kemi Ogunrinde

[Daniel Verse]
Mo gbekele Oluwa
Oju ko ni Timi laialia
Bo ju ba ti gbogbo eniyan
Ojo o ni ti mo lailia
Because

Wa kan dede somi doba
Ni gbogbo ti mo ba ti de
Wa dede mumi Joko o
Pelu omo alade Lai ro ti
Ilekun toti ti ni rere
A dede si won fun mi ni Lai mon
Awon ohun rere to ti nu
A mu won wa lopo

O na ti wa gbe oro mi gba
Ko ti e Yemi, mo o de fe mon
Ona ti wa gbe oro mi gba
Iyanu lo ma jasi
Ona ti wa gbe oro ye gba
Ona o tun lo ma gba wa
Ona ti wa gbe oro ye gba
Iyanu ni Jesu.

[Chorus]
Ona ti o ma gbaye mi gba
Iyanu ni o ma je
Ona ti o ma gbaye mi gba
Iyanu ni
Ona ti o ma gbaye mi gba
Iyanu ni jesu /2x

[Moses Verse]
Ko sohun to lese baba mi
Ona Ara lo gba lo fi ba Joseph se baba
Esteri lo jo yen, Iyanu lo a a se o baba
Ibi ti mi o ro pe mo le de
Fi yanu mu mi debe ju be lo

Iyanu nile, Iyanu lo de, Iyanu lona gbogbo
Seyanu laye mi, Kaye o fo ko di aye Ogo.
Ogo to n womu ogo, mogo jade sa ni o baba.
Ibi okunkun su si laye mi baba tan mole sibe
Ka ba mi yo, ka ba mi dupe laipe ooo.
O na ti o ma gbaye mi gba
Ko ye mi o ye oooo

(Back to Chorus)

[Kemi Verse]
Oba to sede aye
Iyanu nla ni o
Ona to gbe oro Orun gba
Iyanu loje
O mu owo jade lenu eja
Iyanu ni o
O mu omi jade lati inu apata
Iyanu ni o je
Iyefun ororo kan o San gbese
Iyanu ni o
Isede aye to ni, emi gbogbo aye lowo
Iyanu nla loje
Ogo, Ola, oro, o po lode re
mogba
Iyanu nla nbo fun mi o
Eh eh eh
Iyanu nbo fun mi Mo gba
Eeeeeeh.

(Back to Chorus)
Modulation

[Bridge]
Call: Baba mimo, ko sohun to le se
Resp.:Eh Eh Eh Eh
Call: O ji Oku dide, o laju afoju
Resp: Uuuuuuuu
Call: Agbara re, o po ko ma lafiwe
Resp: Eh eh eh
Call: Iyanu Iyanu loruko re Olorun wa
Resp: Ah ah ah ah

Call: Isasun aye, o be lodo ee
Resp: Eh eh eh
Call: Lori o dodo, lo Joko si ooo
Resp: Oh oh oh
Call: Oba a sore fun ni mama siregun ooo
Resp: Eh eh eh
Iyanu Iyanu mani oruko re
(Back to Chorus).

Other Daniel Elubaji Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *