Ija Dopin Ogun Si Tan (Yoruba Hymns)

Ija Dopin Ogun Si Tan

1. Ija dopin oguun si tan
Olugbala jagun molu
Orin ayo la o ma ko
ALLELUIA!

2. Gbogbo ipa n’iku ti lo
Sugbon Kristi f’ogun re
Aye! E ho iho ayo
ALLELUIA!

3. Ojo meta na ti koja
O jinde kuro ninu oku
E f’ogo fun Oluwa wa
ALLELUIA!

4. O d’ewon orun apadi
O silekun orun sile
E korin yin segun re
ALLELUIA!

5. Jesu, nipa iya t’oje
Gba wa lowo oro iku
K’a le ye, ka si ma yin o
ALLELUIA! AMIN.

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *