Lyrics for Emi Mimo By Timi Praise
[Intro]
Emi Olorun sokale wa
Mo gbohun kan,
To n pe mi lato ri oke
Mimo Sinai.
Pe omo Mabo
[Chorus……]
Haaa Baba
Haa Baba
Emi mimo oo bamise
Majeki ifami ororo mi
Koda san bi ti saulu
Majeki ina emi mi
Koku lalayiro Tele
Olorun dakun jare mo Bebe
[Verse]
Wundia mewa layan
Marun fororo o satupa won
Won je ologbon ninu jesu
Marun muu fitila Dani
Layi mororo lowo won
Emi Olorun kosi ninu won
Wa bamise kororo mi madasan,wabamise kororo mi madasan oo Baba
[Chr]
Ahhh baba emi mimo o bami se
Verse2,
Jiji moji
Lori ikunle ni
Mowa o
Jiji moji oo
Moke polodunmare gbo oo
Olorun mi iri ajo
Mi dowo re
Maje n dabi saulu tobOlorun soro towa boku soro
Ki n ma pasan laye mi
Majen pofo mo Bebe
Wa bamise kororo mi
Madasan
Wabamise kororo mi madasan oo baba
Chr……..
Other Timi Praise Polycarp Lyrics
[display-posts category=”Timi Praise” exclude_current=”true”]