Lyrics for Mo wo Ibi ti mo ti bere By Tope Olutokun
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore
Emi o je fogo fe lo miran
Ori won
Ele gbe
Emi o je fogo fe lo miran
Ori won
Ele gbe
Ewa o je fogo fe lo miran
Ori won
Ele gbe
(Adlips)
Ele gbe
Ele gbe
Ele gbe
Ele gbe
Ele gbe
Ele gbe
Ele gbe
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore
Mo wo ibi mo ti bere,
Mo wo ibi mo ba de,
Bi Iye mi o ba si lati yin ooo
A je pe mo ya alaimore