Lyrics : Oluwosan (The Healer) By Seun Hara and The Intimate Worshippers Ft. Olumayowa Dynamic & Eyinjuolodumare
Instrumentals…
SEUNHARA:
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Jesu
Apata Ayeraye
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Jesu
Apata Ayeraye
Back up: Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Jesu
Apata Ayeraye (4times)
Adlip SEUNHARA
O laju afoju
O ma wo aye mu San
Ehhhh
Jesu ooo
Ohun lo Ohun lo
Ehhhh
O ma j’Oku dide ye
Ehhhh
Ohun lo
Jesu Jesu Jesu
Ehhhh
(SeunHara and Eyinjuolodumare Adlips)
EYINJUOLODUMARE
You raised the dead
You heal the blind
Ise re ni
Em’aro lara da
E ji Oku dide
Ise re ni
You healed the blind
You healed the sick
Ise re ni
Ewo Oni sun eje San
Ise re ni
Owo mi San ooooo
Back up : Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Jesu
Apata Ayeraye
EYINJUOLODUMARE ADLIP
O wo mi San ooo
Pata pata pari ola
Onise iyanu
Mimo mimo,mimo lajule orun
Epratha Epratha
Owo mi San oooo
Onise iyanu ni o wo mi San o
Eni to ba mi pade ni bi egun mi,o ti mi sile o
Emi eni a ba ta ka fi ra tupa
Owo mi San ooooo
DYNAMIC
Jesu Jesu
Omo Dafidi
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Jesu Apata Ayeraye
O mu mi lat’aisan,Mo ye, moyege
Lati bu iporuru ati ibanuje
O mu mi ye,Mo yege
Owo mi San
Jesu Apata Ayeraye
Mo le fowo mi gbari
Mo le fowo mi gba’aya
Owo ile mi San
O wo ise mi San
O wo ogbe mi San
O wo okan mi San
O so olokunrun mi da
Ohun loooooo
Jesu Jesu omo Dafidi
SEUNHARA,EYINJUOLODUMARE,DYNAMIC ADLIPS
BACK UPS : Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Ohun lo wo mi San
Jesu
Apata Ayeraye
EYINJUOLODUMARE:CHANTS
TRIO ADLIPS