Skip to content
Home » Popular Yoruba Gospel Songs Lyrics » Ta lo dabi Ire, Jesu

Ta lo dabi Ire, Jesu

    Ta lo dabi Ire, Jesu
    Ta lo da bi ire ooo, Alagbara
    Oba to gbe ogo kari ogo oooo
    Lati inu ogo, lo sinu ogo, oba ti ki su,
    Oba ti ki re, talo dabi ire ooo,
    Alagbara

    Ta lo dabi Ire, Jesu
    Ta lo da bi ire ooo, Alagbara
    Oba to gbe ogo kari ogo oooo
    Lati inu ogo, lo sinu ogo, oba ti ki su,
    Oba ti ki re, talo dabi ire ooo,
    Alagbara

    Leave a Reply

    Your email address will not be published. Required fields are marked *