Lyrics for Oniduro By Sola Allyson
Oni duro mi ese o
Alaanu mi ese o
Iran wo to fun mi ni iranwo ese o
To ba seniyan lo duro eniyan
ati ma kun
To ba seniyan lo duro eniyan
ati ma saroye
My guarrantor
Oni duro mi ese o
Alaanu mi ese o
Iran wo to fun mi ni iranwo ese o
To ba seniyan lo duro eniyan
ati ma kun
To ba seniyan lo duro eniyan
ati ma saroye
Alaanu mi ese
eni towa leyin mi ese o
Eni towa leyin mi ese o
Emi ei ikosile ogba mi ogbemi ro
Emi eni abara kafi ratupa
Aye n wa atupa to ma fi womi Oluwa
Oni duro mi ese o
Emi eni to mo ba ti baye rin lo
Ese o
Omu mi duro lori ese mi
Ma duro ori ese mi titi dale o
Iwo ni igbekele mi koselomin
ese o
Alaanu awon Alaanu mi Oluwa
Ese o
Olurolowo awon Olu rOlowo mi
ese o
Bo ba seniyan lo duro eniyan
ati ma kun
Bo ba seniyan lo duro eniyan
ati ma saroye
Oni duro mi ese o
Video : Oniduro By Sola Allyson
Other Sola Allyson Lyrics
[display-posts category=”Sola Allyson” exclude_current=”true”]
Leave a Reply