Lyrics for Mimo Mimo By Sola Allyson
Mimo Mimo Mimo
S’Olo du mare.
oju elese kole ri ogo re,
Baba Alagbara Baba imole.
hnm hnmm
Majobalo Oluwa
Majobalo Oluwa
Oba takole roloye
Alagbara takole segun ni
Ijoba re dun mowa yeye oooo ma Joba lo oluwa.
Ola lewo laso ogo laso
Ileke iyin legun lesin awa maridi Eledumare.
Tala ba fi o we
Talo le ba o dogba
Olorun to joOlorun lo
Ta la ba fi o we
Other Sola Allyson Lyrics
[display-posts category=”Sola Allyson” exclude_current=”true”]