Lyrics for Igbagbo By Sola Allyson
Igba miran o ma n se mi bii ki n pada seyin
Igba miran o ma n se mi bii ki n jowo Re
Igba ti ‘ji aye ba n ja, bii ki n pada seyin
Igba t’okan mi poruru, bii ki n jowo Re
Sugbon mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s’olododo
Sugbon mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s’olododo
Igbagbo mi duro lori ododo Re
Iwo lapata ayeraye, ibi isadi mi
B’okan mi poruru, ko le p’ase Re da lailai
Iwo s’olododo, mo si mo O ni Alaanu
Igbagbo mi ro mo O, Iwo ni agbara mi
Oke ni mo f’okan si, ibi ti iranwo gbe wa
Fun mi lokun atoke wa, ki n mase pada seyin
Ki n ma sise ninu iriri, ki n mase jowo Re
Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s’olododo
Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s’olododo
Iriri aye a maa fe so ‘yan d’eni o ni ‘gbagbo
Sibe mi o gbeke l’ohun kan leyin agbara Re
Ogbon ori eeyan o le roo ja, eto too ni lailai
Koda b’okan mi se ‘yemeji, ileri too se o duro
Abrahamu, Serah, won rerin looto ntori o dabi pe yeye ni
Sibe won d’eni itokasi fun ibukun pipe
Fun mi lokun atoke wa, Iwo ni Alatileyin
Ki n ma subu, ki n la ajo yi ja, ki n mase jowo Re

Mo mo daju Iwo ni Eni ti kii ko ni sile

Other Sola Allyson Lyrics
[display-posts category=”Sola Allyson” exclude_current=”true”]