Skip to content
Home » Sola Allyson – Eji Owuro Lyrics

Sola Allyson – Eji Owuro Lyrics

  Lyrics for Eji Owuro By Sola Allyson

  Pre-Chorus
  Duro ti mi o, Ololufe
  Ife ti ko labukun ni ko ba mi lo
  Duro ti mi o, Ololufe
  Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo

  Chorus (2x)
  Ife bi eji owuro
  latagbala eledumare lo ti se wa
  Ife to toro minimini
  Ti abawon aiye kan, o le baje o
  Ololufe feran mi, lai se itan o

  Hook (2x)
  Fe mi bi oju ti fe imu
  Fe mi bi irun ti fe ori
  Fe mi bi eyin ti fe nu
  Fe mi temi temi
  Fe mi tokantokan
  Fe mi tara tara
  Ololufe feran mi lai se itan o

  (Repeat chorus) (2x)

  Verse 2
  Ba mi se otito, mo fe o toto
  Ba mi se ododo, mo fe o pelu ododo
  Ba mi se otito, mo fe o toto
  Ba mi se ododo, mo fe o pelu ododo
  Bo ogiri o ba lanu, alangba o le wo ogiri (2x)
  Eleda lo yan wa papo, esu o ni ya wa o

  (Repeat chorus)

  Verse 3
  Ama lowo lowo
  Ama bimo le mo
  Ama se ayo mo ayo
  Ama se ola mo ola
  Ka sha mu ife eledumare se lai se itan

  (Repeat chorus)

  Verse 4
  Gba imoran mi, Ololufe mi
  Oluranlowo la fi mi se fun o, lati orun wa
  Fe ti si omoran mi, Ololufe mi
  Gba imoran mi, Ololufe mi
  Oluranlowo la fi mi se fun o, lati orun wa
  Ka jo rin, ka shogo fun Oruko Olorun
  Alabarin la fi mi she fun ni, lati orun wa
  Mo kan kuro ninu esan aiye, etan o da nkankan fun ni
  Ife ati ope lo le mu alaiye je lai labawon
  Mo kan kuro ninu esan aiye, etan o da nkankan fun ni
  Ife ati ope lo le mu alaiye je lai labawon

  Other Sola Allyson Lyrics
  [display-posts category=”Sola Allyson” exclude_current=”true”]

  Tags:

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *