Ranse Olorun, E lo kede Re (Yoruba Hymn)

1. ‘Ranse Olorun, E lo kede Re
So ti iyanu Oruko nla re
Gb’Oruko Jesu ga, Ajagun-segun
Ogo ‘joba Re ntan, l’aiye at’orun

2. O njoba l’oke O ngbala l’aiye
O si sunmo wa O ngbe inu wa
Ijo nla t’o segun Ko le sai korin
Si Jesu Oba wa t’o raw a pada

3. On l’ope ye fun, Eniti ngbala
Kotin ‘yin soke, Si Olorun wa
Iyin Re l’awon Angeli nko loke
Nwon njuba nwon nwole Fun Od’agutan

4. Jek’a d’ohun po Lati jumo yin
Tire li ogo ati agbara On li ogbon, ope,
At’ola ye fun On lo ye k’a
Feran lai ati lailai.

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *