Lyrics for Ku Ise By Psalmos
Intro
Mo wo waju mi, mo ri owo yin
Mo wo eyin wo, mo ri ife yin
Won wa bere lo wo mi pe bawo ni mo se se
Mo so fun won wipe eeeeee
Emi na ko o Olorun oba ma ni
Olorun oba ma ni
Olorun oba ma ni
Emi na ko o Olorun oba ma ni
Olorun oba ma ni
Olorun oba ma ni
Chorus
Moni Baba kan oo
Moni Baba kan ooo
Baba ara to mo iyi omo
Moni Baba kan oo
Moni Baba kan ooo
Baba ara to mo iyi omo
Moni Baba kan oo
Moni Baba kan ooo
Baba ara to mo iyi omo
Moni Baba kan oo
Moni Baba kan ooo
Baba ara to mo iyi omo
Moni Baba kan oo
Moni Baba kan ooo
Baba ara to mo iyi omo
Moni Baba kan oo
Moni Baba kan ooo
Baba ara to mo iyi omo
Verse 1
Oluwa ku ise
Eh eh eh
Ku isee…
Eh eh eh
Ku isee…
Oooooooooo
Oluwa ku ise oooo
Eh eh eh
Ku isee…
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
(elo o se ye)
Eterete ooo Baba ku ise
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
(elo o se ye)
Eterete ooo Baba ku ise
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
(elo o se ye)
Eterete ooo Baba ku ise
Oluwa ku ise
Iba mi ku ise
Oluwa ku ise
Iba mi ku ise
Ku ise, Ku ise, Ku ise, Ku ise, Ku ise
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
Eterete ooo Baba ku ise
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
Eterete ooo Baba ku ise
Mo de wa so pe
Ni mo de wa so pe oo
Mo de wa so pe
Ni mo de wa so pe oo
O ni kan she lo ore ire bo…
Orun bi o ni…
Emi kan se lore iwo nbo…
Mo de ya so pe oooo ehhh.
(Kenny Kore)
Eyin bi olode o ba ku
Oju ide re kin ru ikoriko
Ko sa aseyin olubori
Ato fi arati bi oke
Ti emi
A le mi no emi
Ti mo fi goke odo afara tanja
Ara efi oju ire wo mi
Eniya efi owo anu kan mi
Emi na ko..
Eledumare ni
Olorun mi ahhh
Baba mi
Eledumare
Ogba gba ti gba alara ilara
Oba aa ji ki
Oba aa ji rii
Ehhh eyin
Ehhh beeee
Chorus
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
Eterete ooo Baba ku ise
Interlude
Oni kan wi o subu
maro guro ehhh
maro guro ehhh
Oooo…ooooooooooo
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Other Psalmos Lyrics
[display-posts category=”Psalmos”]