Ore Wo L’ani Bi Jesu (Yoruba Hymns)

Ore Wo L’ani Bi Jesu
1. Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa!
Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si!
Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po,
Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re.

2. Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi?
A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa.
Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro,
Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa.

3. Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa?
Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa.
Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa.
Yo gbe o soke lapa re, Iwo yo si ri itunu

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *