Ore Wo L’ani Bi Jesu (Yoruba Hymns)

Ore Wo L’ani Bi Jesu

1. Ore wo l’ani bi Jesu,
Ti o ru banuje wa!
Anfani wo lo po bayi
Lati ma gbadura si!
Alafia pupo l’a nsonu,
A si ti je rora po,
Tori a ko fi gbogbo nkan
S’adura niwaju re.

2. Idanwo ha wa fun wa bi?
A ha nni wahala bi?
A ko gbodo so ’reti nu;
Sa gbadura si Oluwa.
Ko s’oloto orebi re
Ti ole ba wa daro,
Jesu ti mo ailera wa;
Sa gbadura s’Oluwa.

3. Eru ha nwo wa l’orun bi,
Aniyan ha po fun wa?
Olugbala je abo wa,
Sa gbadura s’Oluwa.
Awon ore ha sa o ti?
Sa gbadura s’Oluwa.

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *