Ore-ofe B’o Ti Dun To
1. Ore-ofe! b’o ti dun to!
T’o gba em’ abosi;
Mo ti sonu, O wa mi ri,
O si si mi loju.
2. Or’ofe ko mi ki m’beru,
O si l’eru mi lo
B’ore-ofe na ti han to
Nigba mo ko gbagbo!
3. Opo ewu at’ idekun
Ni mo ti la koja;
Or’-ofe npa mi mo doni
Y’o si sin mi dele.
4 Leyin aimoye odun n’be
T’a si nran bi orun,
Gbogb’ ojo tao fi ’yin Re
Y’o ju ’gba ’saju lo.
Amin.
Other Yoruba Hymns Lyrics
[display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]
Leave a Reply