Lyrics for Ipe Mi By Ope Gold
[Chorus]
Olorun ma je n sope danu
Oluwa ma je n fipe sofo
Ki n le sare ije mi lasala..
Ki n gba kaabo omo odorere
[Verse 1]
Ebun nikan o to lati satona ipe
Tori ebun atipe ohun oto loje
O leni ebun sugbon ki o ma gba ipe
Birarewo nje mogba ipe ni
Ooto ni pe a pe o o kilo n fise
Dagaru gbaboru nikan nipe tire
Sora kina re ma baa dokunkun iwo ti a gba dide fun telomiran
[Verse 2]
Sora fun pepe ti o ti n gbadura
Owo o si fun pepe mo bi tigbakan
Isefefe asan ati sekarimi o
Loku ninu ijo baba GBE wa dide
Ifarahan ogo a maa mupe dagba
Katowi ki a to fo onigbowo a de
Ailegbadura a maa muni sina
Ka ma ba a gba ogo sonu laye re
[Verse 3]
Dakun wa o jeka soro isiti
Matori owo so ipe re nu o
Matori owo firo bo ooto mole
Tori ojo kan nbo to ni se a de
Masese lara ipe bolorun soro o
O damiloju wipe koni salai gbo
Fi gbagbo sope ipe mi a dide o…
Tori iranwo orun a dide fun o
Call.:
Ipe mi a dide a si fohun ka gbogbo agbaye ja
Resp:Orimi LA o GBE soke maa saseye loruko jesu
Call:
Ipemi o ni di tan un o ni tan o ki n to tan baba
Call:
Ipe mi a dide a si fohun ka gbogbo agbaye ja
Call:
Opin re ni ka de orun ka si gba kaabo omo odo rere
Call:Mase kan ju ola o ninu ipe re okan ni kogbala o
Video : Ipe Mi By Ope Gold
[embde]
Other Ope Gold Lyrics [display-posts category=”Ope Gold” exclude_current=”true”]
Leave a Reply