Olorun mi
Olorun mi
Iwo loju ti mo fin riran
Iwo ni kokoro ti mo fin shilekun
Iwo lorin ti mo un ko
Ina aye e ko je ko jo mi
Kini mo ni ti mo le fun o o?
Mo wo le mo wa juba re.
Olorun mi
Olorun mi
Olorun mi
Iwo loju ti mo fin riran
Iwo ni kokoro ti mo fin shilekun
Iwo lorin ti mo un ko
Ina aye e ko je ko jo mi
Kini mo ni ti mo le fun o o?
Mo wo le mo wa juba re.
Olorun mi
Leave a Reply