Skip to content
Home » OkikiayanJesu » OkikiayanJesu – Ise Iyanu Ft. Oreoluwani Praise Lyrics

OkikiayanJesu – Ise Iyanu Ft. Oreoluwani Praise Lyrics

  Lyrics for Ise Iyanu By OkikiayanJesu Ft. Oreoluwani Praise

  (Talking Drum Pronounce )

  Kosohun to’lorun olese
  Boba Sojo
  Asoda, aseekan bii otutu
  Aseekan, amu bii oye
  Ko sohun to’lorun olese

  (Instrumental)

  Chorus:
  Yio sele, Iyanu maa sele laye mi (2ce)
  Call&Res

  Solo 1:
  Emi Yio gboju mi sori oke wonni oo
  Nibo niranlowo mi Yio wa tii wa
  Iranlowo mii Yio towo olodumare oba wa, Oba to da orun ohun aye oo
  Ohun Kii Yio je ki Ese mi ki o ye nigbakan kan(rara rarara)

  Oti soro ase jade…. Lodun yiii ooo
  Wipe……

  Chorus
  (Yio sele iyanu maa sele laye mi, Yio sele iyanu maa sele laye mi)

  (Instrumental)

  Solo 2:
  Bibeli lofi ye mi, pe Omo kinihun ama salaini,
  ebi asii maa pa won ni bibeli mi so
  Sugbon awon to ba tii ni oo….kii oo jogun ofoo, gbede lon ro Koko lagbala….
  Ninu odun yii
  Iyanu maa sele ni mo Soo…

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa sele laye mii, Yio sele iyanu maa sele laye mi)

  (Instrumental)

  Solo(OREOLUWA)
  In the history of the bible lati rise iyanu,
  Iyanu akoko nipe..

  Oro manna fawon Omo isrelii oo, oopese mimu ninu igbeyawo,
  Igbeyawo ni canna aati galili ooo yen
  Iwo to so omi dii wine
  Olana setii okun
  Iru ise iyanu woo looti see, mi o tii ri, baba rere baba ke, Iwo lonise iyanu, otidamiloju oma siise iyanu ooooo eeee,
  Oyaa gbogbo eti to gbo mii maa bere fun ise iyanu..

  Gbogbo enu to le so, oyaa maa soro ise iyanu torii Yio sele, Yio sele, Yio sele lodun yiii…..

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa sele laye mii.
  Iyanu toju arii ooo, tetii de maa gbo nii….

  Chorus:
  Yio sele, iyanu maa sele laye mi)
  Gbogbo onise ijoba
  Emaa rona gbegba ooo (Amin)

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa sele laye mii)
  Gbogbo onisowo patapata ee maa rere Oja jee o ooo

  (Chorus: Yio sele Iyanu maa sele laye mi)
  Gbogbo Omo Ile owe
  Eee maa rerin ayooo, lodun yiii

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa sele laye mi)
  Gbogbo alaboyun patapata, emaa towo ala’bosun oooo(pelu iyanu)

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa,sele laye mii)
  Oni’ robinuje okan’
  Odamiloju lo’dun yii waa rii tii ee se.

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa sele laye mi)
  Iwo taati ro pin pe oolebuyoo, lodun yii waa soro soke…

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa sele laye mi)
  Iyanu maa sele, teeti agbo, toju arii, tenu Yio so, lodun yiii oo ooooo

  Chorus:
  Yio sele iyanu maa sele laye mi ooooo.

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *