Skip to content
Home » Ogunmola Babajide – Orisun Ogbon Lyrics

Ogunmola Babajide – Orisun Ogbon Lyrics

  Lyrics for Orisun Ogbon By Ogunmola Babajide

  Chorus:
  Orisun Ogbon, Orisun Oye,
  Orisun Ogbon, Olorun Orisun Oye,
  Oro Nigeria yi o do wo re,
  Orisun Ogbon o Jowo bawa tun to o.

  Ogbon wa ti jawa kule, koma ye wa mo oluwa,
  Asise sise ise wa o mama yo,
  laala yi poju, osise wa dabi ole,
  Orisun Ogbon oo jowo bawa tun to o

  Olorun ko fara ni wa, awa lan nira wa lara,
  Abo lowo oko eru, a tun kora wa leru oo
  Ijinigbe, igbe sumomi yi ti poju Oluwa,
  Orisun Ogbon oo Jowo bawa dasi o e

  Ologun ti see, won o mariise rara o,
  Alagbada tun see nise lotun le koko si o
  Afi kolorun, kobawa da soro yi o,
  Orisun Ogbon o, Jowo bawa tun to ooo

  Ojojumo labiyamo n sunkun o
  Ogun niwa, ogun leyin odowo re,
  Awon oloriwa tise titi, koma ma yo,
  Ajakale arun tao gboruko re ri lo gbode kan,
  Afi kOrisun Ogbon ko bawa yan ju oro yio
  Onisegun nla o, Jowo wa wolee wa san.

  Oni to ba ku ogbon feni keni kobeereo
  Baba a un beere ogbon fawon aladariwa
  Naijiria loruko Jesu gba ite si wa ju
  Olorun mimo o jowo wa wo lee wa san.

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *