Oba Praise – Oba Ft. Kay Wonder Lyrics

Lyrics for OBA (King) By Oba Praise Ft. Kay Wonder

[Chant]
Kabi o osi  Oba Adaniwaye
Omo mo to mo inu eda ti enikan o le mo
The king of the Universe
Oba gbogbo agbaye.

[Prelude]
The earth declares Your Majesty
no one compares to Your royalty.
At the mention of Your name every
knee must bow.
Every tongue confess that You are God.

[Chorus]
Oluwa e tobi(2ce)
Laye lorun o kosoba bi re(4ce)

[Verse 1]
E daa orun ataye
E fi aye se apoti itise Baba
Gbogbo oun ti e da lo n fo ri baale fun o
Ta lo le dun peke nigbati Baba mi ba n dun
iba re oba mi mo se Kabiyesi Oba.
(Repeat chorus)

[Verse 2]
Ipa nla ti o se bi lere Baba
Eniti o se yi pada rara o
Ite re lorun kin te,kin ti o
o lo saalalu bi omi okun alagbalubu o
jija bi iji, E je mo wipe won o ni dun te ba ni o to,
Iyanrin lo sua sua

Ti e ba kaye tan, se won o ni paare ni
Nigbati oun gbogbo ti e ko si ile aye ba tan,
sebi eyin lo maa ku,lo maa ku
Olukangun,Omomoo ti n mo inu igbin
Eti tobi to o.Baba o Baba o,Baba o.
(Repeat Chorus)

[Vamp]
(Call & Response)
Call Kosoba bi re
Res Kosoba bi re

Other Oba Praise Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *