N’nu Gbogbo Ayida Aye (Yoruba Hymns)

N’nu Gbogbo Ayida Aye

N’nu gbogbo ayida aye,
Ayo on wahala;
Iyin Olorun ni y’o ma
Wa l’enu mi titi.

Gbe Oluwa ga pelu mi,
Ba mi gb’Oko Re ga;
N’nu wahala, ‘gba mo kepe,
O si yo mi kuro

Ogun Olorun wa yika
Ibugbe oloto;
Eniti o ba gbekele
Yio sir i ‘gbala

Sa dan ife Re wo lekan
Gbana’ wo o mo pe,
Awon to di oto Re mu
Nikan l’eni ‘bukun.

Eberu Re, enyin mimo,
Eru miran ko si;
Sa ja ki ‘sin Re j’ayo yin,
On y’o ma toju yin.

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *