Lyrics for Ijinle Ninu Ijinle By Niyi Fadipe
Verse 1
Mo gbe o ga o
Meta lokan Ijinle
Kabiyesi re o alaanu mi Ijinle
Ogbanre o |jinle ni
Agbarare o ljinle ni
Orukore o ljinle ni
Okoja Oye eniyan Ijinle ni
Awamaridi 0 ljinle ni
ijinle ninu Ijinle mo gbe o gao
Chorus
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ana mi soro oseun o
Oni mi soro oseun
Ola mi asoro o seun
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Verse 2
Kosoba bire 0
Meta lokan Iwoni Ijinle
Omowo jade Lenu eja o Koyeniyan toriwoni Ijinle
Agbarare o baba |jinle ni
Ogbanre o |jinle ni
Okoja Oye eniyan Ijinle ni
Won wawawa won 0 ri 0 Ijinle ni
Kolafiwe o rarara ljinle ni
Ijinle ninu Ijinle mogbe o ga o
Chorus
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ana mi soro oseun o
Oni mi soro oseun
Ola mi asoro o seun
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ijinle ninu ijinle
O seun o
Ifeoluwa agbato says
I love this song
Oreoluwa says
Interesting
Debby says
It interesting and also touching.i love it
Angela says
Deep! Very touching.🙏😭😭😭
bolarinwa damilola says
So fantantics