Nipa Ife Olugbala (Yoruba Hymns)

Nipa Ife Olugbala

1. Nipa ife Olugbala
Ki yio si nkan
Ojurere re ki pada
Ki yio si nkan
Owon l’eje t’owo wa san
Pipe ledidi or’ofe
Agbara l’owo t’ogba ni
Kole si nkan

2 Bi a wa ninu iponju
ki yio si nkan
Igbala kikun ni tawa
Ki yio si nkan
Igbekele olorun dun,
Gbigbe ninu Kristi l’ere
Emi sin so wa di mimo
Kole si nkan

3 Ojo ola yio  dara
ki yio si nkan
Gbagbo le korin nnu ponji,
Ki yio si nkan
Agbe kele ‘fe baba wa
Jesu fun wa l’ohun gbogbo
Ni yiye tabi ni kiku
Ko le si nkan

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *