Skip to content
Home » Yoruba Hymns » Ngo f’okan ope korin ‘yin (Yoruba Hymns)

Ngo f’okan ope korin ‘yin (Yoruba Hymns)

  1. Ngo f’okan ope korin ‘yin
  Si Oluwa at’Oba mi
  Ngo ma b’awon mimo korin
  F’ohun rere ti Jesu se

  2. Ife Re po si elese
  Iyanu ni, ofe si ni
  O gba mi kuro n’nu egbe
  Ohun rere ni Jesu se

  3. ‘Gbati okan mi ti mo ‘fe Re
  O mu mi to anu Re wo
  Anu ti nko le dupe tan
  Ohun rere ni Jesu se

  4. Gba mo ba de ilu didan
  Ngo ba won ko orin iyin
  Ngo korin na soke kikan
  F’ohun rere ti Jesu se

  Other Yoruba Hymns Lyrics
  [display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *