Skip to content
Home » Yoruba Hymns » L’oju Ale, ‘Gbat’orun Wo (Yoruba Hymns)

L’oju Ale, ‘Gbat’orun Wo (Yoruba Hymns)

    L’oju Ale, ‘Gbat’orun Wo

    L’oju ale, ‘gbat ‘orun wo,
    Won gbe abirun w’odo Re;
    Onirum ni aisan won,
    Sugbon won fayo lo ‘Ie won

    Jesu a de I‘ojo ale yi,
    A sunmo, t’awa t`arun wa,
    Bi a ko tile le ri O,
    Sugbon a mo p’O sunmo wa.

    Olugbala, wo osi wa;
    Omi ko san, mi banuje,
    Omi ko ni ife si O,
    Ife elomi si tutu.

    Omi mo pe, l.sa.n l’aye
    Beni won K0 faye sile,
    Omi l’ore tfko se‘re,
    Beni won ko ii O sore.

    Ko s’okan ninu wa t’o pe,
    Gbogbo WI’ il ni elese;
    Awon t’o ii min O toto,
    Mo ara Won ni alaipe.

    Sugbon Jesu Olugbala
    Eni bi awa n’lwo ‘se,
    ‘Wo ti ri ‘dnnwo bi awa
    ‘Wo si ti mo ailera wa.

    Agbar’ owo Re wa sibe
    Ore Re si li agbara
    Gbo adurl ale wa yi,
    Ni anu, wo gbogbo wa san.

    Other Yoruba Hymns Lyrics
    [display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]

    Leave a Reply

    Your email address will not be published. Required fields are marked *