Kristi, Oluwa Ji Loni, Halleluya (Yoruba Hymns)

Kristi, Oluwa Ji Loni, Halleluya

Kristi, Oluwa ji loni, Halleluya
Eda at” Angeli  nwi Halleluya
Gb”ayo at”isegun ga-Halleluya
Korun at” aye gberin – Halleluya

Ise ti idande tan; Halleluya
O jija, o ti segun; Halleluya
Wo, sisu orun koja-Halleluya
Ko wo sinu eje mo-Halleluya
Lasan n’Iso at’ami’Halleluya
Kris woo run apadi; Halleluya
Lasan l’agbara iku –Halleluya
Kristi si paradise-Halleluya
O tun wa, Oba ogo, Halleluya
“iku itani re da?” Halleluya
Lekan l’O  ku, k’o gba wa, Halleluya
“Boji, isegun re da,? Halleluya

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *