Kilo mu t’omiwa
Kilo mu tomiwaa
Ohun rere lo mu tomiwa
O le iku w’ogbo
O le aarun w’ole
O wa so’banuje mi dayo
Ohun rere lO’mu tomiwa
Abi beeko o?
Aaah, Bee naa ni
Aye mi dara o
Aah, Bee naa ni
Kilo mu t’omiwa
Kilo mu tomiwaa
Ohun rere lo mu tomiwa
O le iku w’ogbo
O le aarun w’ole
O wa so’banuje mi dayo
Ohun rere lO’mu tomiwa
Abi beeko o?
Aaah, Bee naa ni
Aye mi dara o
Aah, Bee naa ni