Lyrics for Kade Pe By Khemigee Ft. David Destiny & OGM
[CHANT]
Ha a,
ki lo wi
Chr:
Call: Ilu ati Jo f’eledumare (X2
Res: Kade pe
Call: ailejo Kama ri rara (X2
Call: let the trumpet blow Tara rara, rara, rara ra ((x2
Call: ailejo Kamari rara
Call: Kade pe Lori Oba ooo (x2
Lead vocal:
(1) mowo Yi ka, molo si sokoto, molo si zamfara,
he, koseni tale fio we,
ninu Oba, ninu ijoye o, ko seni bire
Oba Toto, Oba
nla, alagbada Ina, alawotele orun baba mi,
Apase fOba, asoro gbamu, asoro wamu, owibe sebe ni o,
He, koseni bire o alewilese, Oba towonu abo agbonrin Tobi were
Repeat chr:
Ilu ati Jo
Lead vocal 2:
Alewilese, Oba Toto bi aro, Oba rere bi osu,
Alagbara (X2
Oba to fagi kedari ya o, alagbara nla,
Mowo le,
moyika,
mOba rubu rubu fOba Toto Oba
Alewilese,
seriki duniyan,
eze ukwu
AtObajaiye,
atosebi Oba
Koseni tale fio jo,
Eleyinju ege,
Oba to fine,
Oba to yekeable,
Oba to fine,
supernatural God o
Res: Kade pe
Call: Oba tewu oso darugbo
Call: Adagba Malo digi, adagba Malo gilasi
Call: he, Oba (x4, alara gbayida, Oba nio, koseni tale fio we
Call: Jesu mo wa wo,
mo wokun,
mo wose,
iwo rolagbara,
iwo rotobi,
Jesus peeeeeee
Call: Omorihi avo, nda, avo.
Other Khemigee Lyrics
[display-posts category=”Khemigee” exclude_current=”true”]