Jerusalem T’orun (Yoruba Hymns)

Jerusalem T’orun
1. Jerusalem t’orun
L’orin mi, ilu mi
Ile mi bi mba ku
Ekun Ibukun mi

Ibi ayo
Nigbawo ni
Nr’oju Re
Olorun mi?

2. Nibe l’Oba mi wa
T’ada lebi laye
Angeli nkorin fun
Won si nteriba fun

3. Pataki igbani
Pari irin ajo won nibe
Awon woli won woo
Omo Alade Alaafia

4. Nibe ni imole ri
Awon Aposteli
At’awon akorin
Ti nlu harpu wura

5. Ni igbala wonni
Ni awon martir wa
Won wo aso nla
Ogo bo ogbe won

6. T’emi yi wasu mi
Ti mo ngb’ ago Kedar
Ko si ‘ru yi loke
Nibe ni mo fe lo

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *