1. Iwo Olurapada wa
Awa ti fe O to
Oruko Re ti dun po to
Ju yi t’a le rohin
2. A ba le ma gbo ohun Re
Ti anu Re si wa
Olori Alufa wan la
Ninu Re l’ao ma yo
3. Jesu Iwo lo rin wa,
‘Gbat’a wa l’aiye yi
Iwo ni y’o je orin wa
‘Gbat’aiye ba koja
4. ‘Gbat’a ba si gunle loke
Pel’awon ayanfe
Kristi ni y’o je orin wa
T’a o ma ko titi
Other Yoruba Hymns Lyrics
[display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]
Leave a Reply