Site icon GMLyrics

Isegun Wa Li Okan Mi (Yoruba Hymns)

Isegun Wa Li Okan Mi (Yoruba Hymns)

Isegun Wa Li Okan Mi

1. Isegun wa li okan mi
Isegun wa li okan mi
Nitori emi ngbe nu mi
Je ki igbi idanwo de
Jesu mura lati gba mi.

Egbe
Isegun! Isegun!  ‘Segun L’okan mi
Moni isegun nla tori Jesu
gb okan mi
Isegun! Isegun! bi odo sisan
Moni segun nla ninu eje Jesu.

2. Bi ‘ja tile le t’o sipe
B’esu tile b’ okan mi ja;
Sibe, mo je alagbara,
L’agbara Jesu, ngo segun.

3. Mo ni’ segun lori ese
Mo ni’segun lori boji,
Ani iku ko nipa mo
Halleluya! emi ti la.

Other Yoruba Hymns Lyrics
[display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]

Exit mobile version