Site icon GMLyrics

Ipinle ti Jesu Fi lele leyi

Ipinle ti Jesu Fi lele leyi

1: Ipinle ti Jesu fi le’le l’eyi
Ti baba Aladura nto,
K’eda mase ro pe
O ye kuro nibe, o duro le Krist’ apata;

Chorus:
Kerubu eyo, Serafu eyo
A fi ‘pile lele lori otito
Kerubu eyo, Serafu eyo
A fi ‘pile lele lori otito

2. Bi ara nsan egbagbeje ohun
Omo Jesu yio duro ti,
K’enia ma kegan oko Noah
Oko refo omo Jesu la.

Chorus:

3. A rojo mo Mose, A rojo mo Peter,
A rojo mo Jesu Oluwa
A rojo mo Mose Orimolade
K’eda Ko kiye s’ara.

Chorus:

4. Baba Aladura dide damure
Lati pade awon Kerubu
Olorun ti yin ise re lat’oke wa
Ade iye yio je tire

Chorus:

5. B’aiye mbu Mose awon Angeli nfe
Olorun Abraham nfe
Awon ogun orun si ngbadura re
Olorun metalokan.

 

1: Ipinle ti Jesu fi le’le l’eyi
Ti baba Aladura nto,
K’eda mase ro pe
O ye kuro nibe, o duro le Krist’ apata;

Chorus:
Kerubu eyo, Serafu eyo
A fi ‘pile lele lori otito
Kerubu eyo, Serafu eyo
A fi ‘pile lele lori otito

2. Bi ara nsan egbagbeje ohun
Omo Jesu yio duro ti,
K’enia ma kegan oko Noah
Oko refo omo Jesu la.

Chorus:

3. A rojo mo Mose, A rojo mo Peter,
A rojo mo Jesu Oluwa
A rojo mo Mose Orimolade
K’eda Ko kiye s’ara.

Chorus:

4. Baba Aladura dide damure
Lati pade awon Kerubu
Olorun ti yin ise re lat’oke wa
Ade iye yio je tire

Chorus:

5. B’aiye mbu Mose awon Angeli nfe
Olorun Abraham nfe
Awon ogun orun si ngbadura re
Olorun metalokan.

Exit mobile version