Skip to content
Home » Hossana Voice – Oba Lyrics

Hossana Voice – Oba Lyrics

  Lyrics : Oba By Hossana Voice

  Oba o oba, jesu mi ni oba
  Oba o oba, jesu mi ni oba
  Alade ogo eledumare
  Iwo lope ye.
  Alade ogo awi mayewun
  To to o iba oba.

  You are not the king of England
  You are the king of this land

  You are not alafin of Oyo
  Eyin ni alafin of orun.
  You are not ooni of Ife
  Eyin ni ooni of the universe.

  E oki se alake of Eba
  Eyin ni alade of Orun.

  Eyin loba laye lorun gbogbo awon tin je oba laye lorun, sebi oruko afi je lasan ni.
  Eyin loba alade ina,
  Oni bata ide
  Sebi iji sha legun leshin o,
  Arugbo ojo, adagba ma paro oye,
  E eleti gbohun gbaroye gbo
  Orin ope ni mo mu wa o
  Ma ma mu nu olorun dun
  Ma ma mu nu olorun dun
  E mi ma mu nu olorun dun
  Pelu iyin mi lojojumon.

  Ma ma mu nu olorun dun
  Ma ma mu nu olorun dun

  E mi ma mu nu olorun dun
  Pelu iyin mi lojojumon
  Babalawo mu nu ifa e dun
  Oni shegun mu nu opele dun,
  Ka wa na ma mu nu olorun dun
  Pelu iyin mi lojojumon.
  Babalawo mu nu ifa e dun
  Oni shegun mu nu opele dun
  Ke mi na ma mu nu olorun dun
  Pelu iyin mi lojojumon.

  Ma ma mu nu olorun dun
  Ma ma mu nu olorun dun
  Ma ma mu nu olorun dun
  Pelu iyin mi lojojumon.

  Ewo orun ti shi
  E mi rawon angeli ni orun

  Pelu agbagba merinlelogun loke orun o
  Won mu nu olorun dun
  Won mu o wun iyin won dani pelu iga adura awa olodo
  Won ke mimo mimo soba eledumare,
  Won mu nu olorun dun.

  Ma ma mu nu olorun dun
  Ma ma mu nu olorun dun
  Ma ma mu nu olorun dun
  Pelu iyin mi lojojumon

  I will make my God happy
  I will make my God happy
  I will make my God happy
  With my praises everyday.

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *