Ha Egbe Mi, E W’asia (Yoruba Hymns)

Ha Egbe Mi, E W’asia

1. Ha! Egbe mi, e w’ asia
Bi ti nfe lele!
Ogun ‘ranwo sunmo tosi,
A fere segun!

Egbe
D’odi mu, Emi fere de
Beni Jesu nwi,
Ran ‘dahun pada s’ orun pe,
Awa o dimu!

2. Wo opo ogun ti mbowa,
Esu nko won bo;
Awon alagbara nsubu,
A fere damu.

3. Wo asia Jesu ti nfe;
Gbo ohun ipe;
A o segun gbogbo ota
Li oruko Re.

4. Ogun ngbona girigiri,
Iranwo w ambo;
Balogun wa mbowa tete
Egbe tujuka.

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *