Skip to content
Home » Hanna Soyombo » Hanna Soyombo – Ona Iye Lyrics

Hanna Soyombo – Ona Iye Lyrics

    Lyrics for Ona Iye By Hanna Soyombo

    [Chorus]
    Jesu ni ona iye… 4x
    To lo si’joba orun
    Call: Jesu ni ona iye… 2x
    Response: Jesu ni ona iye

    To lo si’joba orun
    Call: elese gbaa gbo o
    Ki o le ri iye
    Response: Jesu ni ona iye
    To lo si’joba orun

    Call: Apaniyan yi pada
    Ko wa gba Jesu s’aye re
    Response….
    Call: Alagbere yi pada
    Jesu n pe o loni
    Response……
    Call: oni lojo igbala re o
    Ola le pe ju fun o
    Response….

    Call: enikeni to ba gba a gbo o
    Yi o d’eni iye
    Response…
    Call: sa asala f’emi re
    Ki ojo eru to de o
    Response….

    Jesu mbo! l’ofurufu pe, l’ayo
    Ojo ayo! ojo ayo!
    Awon t’o fe y’o fo lo pade Re
    Ojo ayo! ojo nla
    Nwon y’o pade Oluwa ni sanma
    Gbogbo wa pelu Jesu y’o wa nibe,
    A o bo lowo aniyan at’aro
    Ojo ayo! ojo nla!

    Awon miran ko ni le ba wa ko
    Orin ayo ti ojo na
    Sugbon gbogbo wa ni ayo mbe, fun
    Ojo ayo! Ojo nla!
    ‘Tori Jesu nduro sibesibe
    K’a le mura tan nipa agbara Re…….

    Other Hanna Soyombo Lyrics
    [display-posts category=”Hanna Soyombo” exclude_current=”true”]

    Leave a Reply

    Your email address will not be published. Required fields are marked *