Skip to content
Home » Gloria Bamiloye » Gloria Bamiloye – Esu To Ba Gbemi Lyrics

Gloria Bamiloye – Esu To Ba Gbemi Lyrics

  Lyrics for Esu To Ba Gbemi By Gloria Bamiloye

  Esu to ba gbemi, too gbe mi, too gbemi
  Esu to ba gbemi, oo le lami mole o
  Esu to ba gbemi, too gbe mi, too gbemi
  Esu to ba gbemi, oo le lami mole o

  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole
  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole
  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole
  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole

  Iya to ba gbe mi, too gbe mi, too gbemi.
  Iya to ba gbe mi, oo le la mi mole o

  Ese to ba gbe mi too gbe mi, too gbemi.
  Ese to ba gbe mi, oo le lami mole o

  (Adlibs)
  Nitori naan, Olorun si ti gbe ga gidigidi
  O si ti fun ni oruko to ju gbogbo oruko
  Pe ni oruko Jesu ni ki gbogbo eegun ki o maa kunle
  Awon ni tin be ni orun, ati awon ni tin be ni Ile
  Ati awon ni tin be nisale ile.

  Ati Pe ki gbogbo ahon ki o maa jewo Pe Jesu Kristi
  Ni oluwa wun ogo Olorun Baba
  Oruko Jesu ni oruko to ju gbogbo oruko love
  Oun ni olugbala re, Oti ku, ositi ji nde

  Oti jiya Nitori tiwa He Paid the price on the cross
  Oti fun wa ni isegun, Jesu mi oruko re

  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole
  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole

  Esu to ba gbemi, too gbe mi, too gbemi.
  Esu to ba gbemi, oo le lami mole o

  (Adlibs)
  Ti o ba Lee gba ise ori igi agbelebu yii gbo
  Ti o si if aye re fun, ko si Oun ti Esu Lee fi o se.
  Tabi oun ti o Lee muwa si aye re, ose lasan ni
  Iwo saa ti gba ni Oluwa ati igbala re
  Yoo si ko Ese re sile, kiyoo siji bowo
  Yo O si fun o ni isegun
  Ko wa si, be esu, iya, Arun, ese se le gbe o to.

  Kole lao mole Rara, tori Pe asegun ni o ninu Jesu Kristi Oluwa

  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole
  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole
  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole
  Jesu ti la o mole o, oo le lami mole

  Other Gloria Bamiloye Lyrics
  [display-posts category=”Gloria Bamiloye” exclude_current=”true”]

  Tags:

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *