Gbogbo Aye, Gbe Jesu Ga (Yoruba Hymns)

Gbogbo Aye, Gbe Jesu Ga

1.Gbogbo aye, gbe Jesu ga
Angeli ewole fun
Emu ade Oba re wa
Se l’Oba awon Oba

2. Ese lOba eyin martyr
Ti npe ni pepe re
Gbe gbongbo igi, Jesse ga
Se l’Oba awon Oba

3. Eyin irun omo Israeli
Ti a ti rapada
Eki eni t’o gba yin la,
Se l’Oba awon Oba

4. Gbogbo eniyan elese
Ranti banuje yin
Ete ‘kogun yin sese re
Se l’Oba awon Oba

5. Ki gbogbo orile ede
Ni gbogbo agbaye
Ki won ki, “Kabiyesile
Se l’Oba awon Oba

6. A bale pe l’awon t’orun
Lati ma juba re
K’a bale jo jumo korin
Se l’Oba awon Oba

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *