Site icon GMLyrics

Gbogbo aiye gbe Jesu ga (Yoruba Hymn)

Gbogbo aiye gbe Jesu ga (Yoruba Hymn)

1. Gbogbo aiye gbe Jesu ga
Angeli, e wole fun
Emu ade oba re wa
Se l’oba ‘won ba

2. Enyin t’e ku f’eri Kristi
T’oyi pepe re ka
Gbe gbongbo Jesse ga
Se l’Oba ‘won oba

3. Enyin iru-omo Isreal
Ti a ti rapada
E ki Enit’o gba nyin la
Se l’Oba ‘won oba

4. Gbogbo enia elese
Ranti ‘banuje nyin
E te ‘kogun nyin s’ese Re
Se l’Oba ‘won oba

5. Ki gbogbo orile-ede
Ni gbogbo agbaiye
Ki won ki “Kabiyesile”
Se l’Oba ‘won oba

6. A ba le pel’awon t’orun
Lati ma juba Re
K’a ba le jo jumo korin
Se l’Oba ‘won oba

Exit mobile version