Skip to content
Home » Gbenga Akinfenwa » Gbenga Akinfenwa – Iba Ft. Olayiwola Jagun Lyrics

Gbenga Akinfenwa – Iba Ft. Olayiwola Jagun Lyrics

    Lyrics for Iba By Gbenga Akinfenwa Ft. Olayiwola Jagun

    Morababa, Morababa
    Eledumare ooo
    To to ola re ba
    Iba, iba fun o ooo
    Toto ola re iba

    Awon angeli won f’ori bale
    To to ola re ba
    Iba, iba fun o ooo
    Toto ola re iba

    Morababa, Morababa
    Olutoju eniyan
    To to ola re ba
    Iba, iba fun o ooo
    Toto ola re iba

    To to ola re ba
    Iba, iba fun o ooo
    Toto ola re iba

    To to ola re iba
    Iba, iba fun o ooo
    Toto ola re iba

    To to ola re iba
    Iba, iba fun o ooo
    Toto ola re iba

    Iba akoda aye oo, iba
    Iba aseda orun oo, iba
    Ato to gboju le, iba
    Ato to farati, iba
    Ato to feyin ti, iba
    Ato f’ise ogun ran, iba
    Asiwaju ogun lalo, iba
    Akeyin ogun labo, iba
    Oranmonise fayati, iba
    Oranmonise pon’mo seyin, iba
    Awo igba’run ma gbeje, iba
    Awo igba’run ma gbeje ooo, iba
    Olowo pin’re pin’re, iba
    Olowo ro’bi ro’bi, iba
    O pin’re, pin’re kanmi ooo, iba
    O pin’re, pin’re kan e ooo, iba

    Iba, iba, iba, iba
    Iba, iba, iba, iba
    Iba, iba, iba, iba

    Diving Eulogy

    Morababa, Morababa
    Eledumare ooo
    To to ola re ba
    Iba, iba fun o ooo
    Toto ola re iba

    Leave a Reply

    Your email address will not be published. Required fields are marked *