Gbat’agbara Olorun De (Yoruba Hymns)

Gbat’agbara Olorun De

1. Gbat’ agbara Olorun de
Li ojo Pentikosti
Sa ifoju sona pari
Tori won ri Emi gba

Egbe
Ran agbara Oluwa
Ran agbara Oluwa
Ran agbara Oluwa
Ki o si baptis wa

2. Ela ‘han ina be le won
Won si wasu oro na
Opolopo enia gbagbo
Won yi pada s’ Olorun
Ran agbara Oluwa

3. A nwona fun Emi Mimo
Gbogbo wa f’ohun sokan
Mu ‘leri na se Oluwa
Ti a se nin’oro Re
Ran agara Oluwa

4. Jo fi agbara Re kun wa
Fun wa ni ‘bukun t’a nfe
Fi ogo Re kun oka wa
B’a ti nfi’ bagbo bebe
Ran agbara Oluwa

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *