Eje K’a F’inu Didun (Yoruba Hymns)

Eje K’a F’inu Didun
1. Eje k’a f’inu didun
Yin Oluwa Olore

[Egbe]
Anu Re O wa titi
Lododo dajudaju

2. On nipa agbara Re
F’imole s’aye titun

3. O mbo gbogb’eda ‘laye
O npese fun aini won

4. O bukun ayanfe Re
Li aginju iparun

5. E je k’a f’inu didun
Yin Oluwa Olore

Other Yoruba Hymns Lyrics

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *